Idanileko yi so nipa awon nkan wonyi:(1) Itumo Ayanmo.(2) Gbigba ayanmo ni ododo je okan ninu awon origun igbagbo.(3) Olohun ti O da awa eda ni O da awon ohun ti a n se ni ise.(4) Awon ipele Ayanmo.(5) Ninu awon idi ti Olohun fi se Ayanmo ni ohun asiri ati ipamo.
Show More
Creators & Guests
We don't know anything about the creators of this podcast yet. You can so they can be credited for this and other podcasts.