1- Ninu abala yi ọrọ waye lori wipe ounjẹ ti Ọlọhun Allah pese fun wa idẹra ni o jẹ ati alaye idi ti o fi jẹ idẹra. Bakannaa awọn nkan ti o dara pupọ lati se akiyesi rẹ nigba ti a ba fẹ jẹ ounjẹ.2- Abala yii jẹ itẹsiwaju alaye lori awọn ẹkọ ti o rọ mọ jijẹ ati mimu, ẹkunrẹrẹ alaye si waye lori awọn nkan ti o dara pupọ lati jina si ni asiko ti a ba fẹ jẹ tabi mu.
Show More
Creators & Guests
We don't know anything about the creators of this podcast yet. You can so they can be credited for this and other podcasts.