1- Alaye waye ni agbegbe yii lori itan ranpẹ nipa ẹni tii se iya-iya Anọbi Isa ati iya rẹ pẹlu alaye nipa bi bibi rẹ se waye.2- Ọrọ waye ni abala yii nipa awọn isẹ iyanu ti Ọlọhun se lati ọwọ Anọbi Isa. Ibeere si waye wipe se ọmọ Ọlọhun ni Anọbi Isa bi?3- Idanilẹkọ ni agbegbe yii pese idahun si awọn ibeere wọnyii:- Njẹ Anọbi Isa ku ati wipe nibo ni o ku si?- Njẹ Anọbi Isa npada bọ wa si aye, ati wipe igba wo ni?- Ki ni yoo sẹlẹ ni asiko pipadabọọ rẹ?- Awọn ẹri ti o da lori pipadabọọ rẹ.
Show More
Creators & Guests
We don't know anything about the creators of this podcast yet. You can so they can be credited for this and other podcasts.